Iṣe Apo 26:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwà aiye mi lati igba ewe mi, bi o ti ri lati ibẹrẹ, lãrin orilẹ-ede mi ati ni Jerusalemu, ni gbogbo awọn Ju mọ̀.

Iṣe Apo 26

Iṣe Apo 26:2-10