Iṣe Apo 26:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Paulu wipe, Ori mi kò bajẹ, Festu ọlọlá julọ; ṣugbọn ọ̀rọ otitọ ati ti ìwa airekọja li emi nsọ jade.

Iṣe Apo 26

Iṣe Apo 26:15-32