Iṣe Apo 26:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

AGRIPPA si wi fun Paulu pe, A fun ọ làye lati sọ ti ẹnu rẹ. Nigbana ni Paulu nawọ́, o si sọ ti ẹnu rẹ̀ pe:

Iṣe Apo 26

Iṣe Apo 26:1-5