Iṣe Apo 25:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ ni ijọ keji, ti Agrippa on Bernike wá, ti awọn ti ọsọ́ pipọ, ti nwọn si wọ ile ẹjọ, pẹlu awọn olori ogun, ati awọn enia nla ni ilu, Festu paṣẹ, nwọn si mu Paulu jade.

Iṣe Apo 25

Iṣe Apo 25:20-27