Iṣe Apo 25:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati Paulu fi ọ̀ran rẹ̀ lọ Augustu, pe ki a pa on mọ fun idajọ rẹ̀, mo paṣẹ pe ki a pa a mọ titi emi o fi le rán a lọ sọdọ Kesari.

Iṣe Apo 25

Iṣe Apo 25:18-23