Iṣe Apo 25:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nwọn ni ọ̀ran kan si i, niti isin wọn, ati niti Jesu kan ti o ti kú, ti Paulu tẹnumọ́ pe o wà lãye.

Iṣe Apo 25

Iṣe Apo 25:12-27