Iṣe Apo 25:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Festu lẹhin ti o ti ba ajọ igbìmọ sọ̀rọ, o dahùn pe, Iwọ ti fi ọ̀ran rẹ lọ Kesari: lọdọ Kesari ni iwọ ó lọ.

Iṣe Apo 25

Iṣe Apo 25:9-17