Iṣe Apo 25:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Paulu si wipe, Niwaju itẹ́ idajọ Kesari ni mo duro nibiti o yẹ ki a ṣe ẹjọ mi: emi kò ṣẹ awọn Ju, bi iwọ pẹlu ti mọ̀ daju.

Iṣe Apo 25

Iṣe Apo 25:1-11