Iṣe Apo 24:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

O paṣẹ ki awọn olufisùn rẹ̀ wá sọdọ rẹ: lati ọdọ ẹniti iwọ ó le ni oye gbogbo nkan wọnyi, nitori ohun ti awa ṣe fi i sùn nigbati iwọ ba ti wadi ẹjọ rẹ̀.

Iṣe Apo 24

Iṣe Apo 24:2-18