Iṣe Apo 24:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si nreti pẹlu pe a ba fun on li owo lati ọwọ́ Paulu wá, ki on ki o le da a silẹ: nitorina a si ma ranṣẹ si i nigbakugba, a ma ba a sọ̀rọ.

Iṣe Apo 24

Iṣe Apo 24:18-27