Iṣe Apo 24:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi kò ṣe bẹ̃, jẹ ki awọn enia wọnyi tikarawọn sọ iṣe buburu ti nwọn ri lọwọ mi, nigbati mo duro niwaju ajọ igbimọ yi,

Iṣe Apo 24

Iṣe Apo 24:12-22