Iṣe Apo 24:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati a si ti pè e jade, Tertulu bẹ̀rẹ si ifi i sùn wipe, Bi o ti jẹ pe nipasẹ rẹ li awa njẹ alafia pipọ, ati pe nipasẹ itọju rẹ a nṣe atunṣe fun orilẹ yi.

Iṣe Apo 24

Iṣe Apo 24:1-12