Iṣe Apo 24:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Larin wọnyi ni nwọn ri mi ni iwẹnu ni tẹmpili, bẹ̃ni kì iṣe pẹlu awujọ, tabi pẹlu ariwo.

Iṣe Apo 24

Iṣe Apo 24:11-19