Iṣe Apo 24:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn eyi ni mo jẹwọ fun ọ, pe bi Ọna ti a npè ni adamọ̀, bẹ̃li emi nsìn Ọlọrun awọn baba wa, emi ngbà nkan gbogbo gbọ́ gẹgẹ bi ofin, ati ti a kọ sinu iwe awọn woli:

Iṣe Apo 24

Iṣe Apo 24:10-21