Iṣe Apo 23:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati Paulu ṣakiyesi pe, apakan wọn jẹ Sadusi, apakan si jẹ Farisi, o kigbe ni igbimọ pe, Ará, Farisi li emi, ọmọ Farisi: nitori ireti ati ajinde okú li a ṣe ba mi wijọ.

Iṣe Apo 23

Iṣe Apo 23:1-13