Iṣe Apo 23:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati a si ti sọ fun mi pe, nwọn ó dèna dè ọkunrin na, ọgan mo si rán a si ọ, mo si paṣẹ fun awọn olufisùn rẹ̀ pẹlu, lati sọ ohun ti nwọn ba ri wi si i niwaju rẹ.

Iṣe Apo 23

Iṣe Apo 23:29-34