Iṣe Apo 23:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, Awọn Ju fi ìmọ ṣọkan lati wá ibẹ̀ ọ ki o mu Paulu sọkalẹ wá si ajọ igbimọ li ọla, bi ẹnipe iwọ nfẹ bère nkan dajudaju nipa rẹ̀.

Iṣe Apo 23

Iṣe Apo 23:14-24