Iṣe Apo 23:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

O mu u, o si sìn i lọ sọdọ olori-ogun, o si wipe, Paulu ondè pè mi sọdọ rẹ̀, o si bẹ̀ mi pe ki emi mu ọmọkunrin yi tọ̀ ọ wá, ẹniti o ni nkan lati sọ fun ọ.

Iṣe Apo 23

Iṣe Apo 23:15-26