Iṣe Apo 23:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si tọ̀ olori awọn alufa ati awọn àgbagba lọ, nwọn si wipe, Awa ti fi èpe nla bu ara wa pe, a kì yio tọ́ ohun nkan wò titi awa ó fi pa Paulu.

Iṣe Apo 23

Iṣe Apo 23:8-18