Iṣe Apo 22:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. ẸNYIN ará, ati baba, ẹ gbọ ti ẹnu mi nisisiyi.

2. (Nigbati nwọn si gbọ́ pe o mba wọn sọrọ li ede Heberu, nwọn tubọ parọrọ; o si wipe,)

Iṣe Apo 22