Iṣe Apo 21:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni ijọ keji awa lọ kuro, a si wá si Kesarea: nigbati awa si wọ̀ ile Filippi Efangelisti, ọkan ninu awọn meje nì; awa si wọ̀ sọdọ rẹ̀.

Iṣe Apo 21

Iṣe Apo 21:7-11