Iṣe Apo 21:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati a si ti lò ọjọ wọnni tan, awa jade, a si mu ọ̀na wa pọ̀n; gbogbo nwọn si sìn wa, pẹlu awọn obinrin ati awọn ọmọde titi awa fi jade si ẹhin ilu: nigbati awa si gunlẹ li ebute, awa si gbadura.

Iṣe Apo 21

Iṣe Apo 21:4-15