Iṣe Apo 21:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn kan nkígbe ohun kan, awọn miran nkigbe ohun miran ninu awujọ: nigbati kò si le mọ̀ eredi irukerudò na dajudaju, o paṣẹ ki nwọn ki o mu u lọ sinu ile-olodi.

Iṣe Apo 21

Iṣe Apo 21:31-40