Iṣe Apo 21:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lojukanna o si ti mu awọn ọmọ-ogun ati awọn balogun ọrún, o si sure sọkalẹ tọ̀ wọn lọ: nigbati nwọn si ri olori ogun ati awọn ọmọ-ogun, nwọn dẹkun lilu Paulu.

Iṣe Apo 21

Iṣe Apo 21:31-40