Iṣe Apo 21:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ọjọ meje si fẹrẹ pé, ti awọn Ju ti o ti Asia wa ri i ni tẹmpili, nwọn rú gbogbo awọn enia soke, nwọn nawọ́ mu u.

Iṣe Apo 21

Iṣe Apo 21:22-28