Iṣe Apo 21:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ninu awọn ọmọ-ẹhin lati Kesarea ba wa lọ, nwọn si mu Mnasoni ọmọ-ẹhin lailai kan pẹlu wọn, ará Kipru, lọdọ ẹniti awa ó gbé wọ̀.

Iṣe Apo 21

Iṣe Apo 21:6-26