Iṣe Apo 20:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ni ọjọ ikini ọ̀sẹ nigbati awọn ọmọ-ẹhin pejọ lati bù akara, Paulu si wasu fun wọn, o mura ati lọ ni ijọ keji: o si fà ọ̀rọ rẹ̀ gùn titi di arin ọganjọ.

Iṣe Apo 20

Iṣe Apo 20:1-15