Iṣe Apo 20:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sopateru ara Berea ọmọ Parru si ba a lọ de Asia; ati ninu awọn ara Tessalonika, Aristarku on Sekundu; ati Gaiu ara Derbe, ati Timotiu; ati ara Asia, Tikiku on Trofimu.

Iṣe Apo 20

Iṣe Apo 20:1-14