Iṣe Apo 20:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ kiyesara nyin, ati si gbogbo agbo ti Ẹmí Mimọ́ fi nyin ṣe alabojuto rẹ̀, lati mã tọju ijọ Ọlọrun, ti o ti fi ẹ̀jẹ ara rẹ̀ rà.

Iṣe Apo 20

Iṣe Apo 20:27-33