Iṣe Apo 20:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ti mo nsọ fun awọn Ju, ati fun awọn Hellene pẹlu, ti ironupiwada sipa Ọlọrun, ati ti igbagbọ́ sipa Jesu Kristi Oluwa wa.

Iṣe Apo 20

Iṣe Apo 20:17-29