Iṣe Apo 20:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si de ọdọ rẹ̀, o wi fun wọn pe, Ẹnyin tikaranyin mọ̀, lati ọjọ ikini ti mo ti de Asia, bi emi ti ba nyin gbé, ni gbogbo akoko na,

Iṣe Apo 20

Iṣe Apo 20:13-23