Iṣe Apo 20:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awa si ṣaju, awa si ṣikọ̀ lọ si Asso, nibẹ̀ li a nfẹ gbà Paulu si ọkọ̀: nitori bẹ̃li o ti pinnu rẹ̀, on tikararẹ̀ nfẹ ba ti ẹsẹ lọ.

Iṣe Apo 20

Iṣe Apo 20:11-22