Iṣe Apo 20:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NIGBATI ariwo na si rọlẹ, Paulu ranṣẹ pè awọn ọmọ-ẹhin, o si gbà wọn ni iyanju, o dagbere fun wọn, o dide lati lọ si Makedonia.

Iṣe Apo 20

Iṣe Apo 20:1-9