Iṣe Apo 2:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina bi a ti fi ọwọ́ ọtún Ọlọrun gbe e ga, ti o si ti gbà ileri Ẹmí Mimọ́ lati ọdọ Baba, o tú eyi silẹ, ti ẹnyin ri, ti ẹ si gbọ́.

Iṣe Apo 2

Iṣe Apo 2:28-35