Iṣe Apo 2:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti iwọ ki yio fi ọkàn mi silẹ ni ipò-okú, bẹ̃ni iwọ ki yio jẹ ki Ẹni-Mimọ́ rẹ ki o ri idibajẹ.

Iṣe Apo 2

Iṣe Apo 2:19-32