Iṣe Apo 2:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori Dafidi ti wi nipa tirẹ̀ pe, Mo ri Oluwa nigba-gbogbo niwaju mi, nitoriti o mbẹ li ọwọ́ ọtún mi, ki a mà bà ṣí mi ni ipò:

Iṣe Apo 2

Iṣe Apo 2:24-28