Iṣe Apo 19:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Paulu si gbe ọwọ́ le wọn, Ẹmí Mimọ́ si bà le wọn; nwọn si nfọ̀ ède miran, nwọn si nsọ asọtẹlẹ.

Iṣe Apo 19

Iṣe Apo 19:5-11