Iṣe Apo 19:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn olori kan ara Asia, ti iṣe ọrẹ́ rẹ̀, ranṣẹ si i, nwọn bẹ̀ ẹ pe, ki o máṣe fi ara rẹ̀ wewu ninu ile ibiṣire.

Iṣe Apo 19

Iṣe Apo 19:25-35