Iṣe Apo 19:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ọkunrin kan ti a npè ni Demetriu, alagbẹdẹ fadaka, ti ima fi fadaka ṣe ile-oriṣa fun Diana, o mu ère ti kò mọ̀ ni iwọn fun awọn oniṣọnà wá;

Iṣe Apo 19

Iṣe Apo 19:22-25