Iṣe Apo 19:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ọkunrin ti ẹmi buburu wà lara rẹ̀ si fò mọ́ wọn, o ba wọn dimú, o bori wọn, bẹ̃ni nwọn sá jade kuro ni ile na ni ìhoho ati ni ifarapa.

Iṣe Apo 19

Iṣe Apo 19:12-24