Iṣe Apo 19:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tobẹ̃ ti a fi nmu gèle ati ibantẹ́ ara rẹ̀ tọ̀ awọn olokunrun lọ, arùn si fi wọn silẹ, ati awọn ẹmi buburu si jade kuro lara wọn.

Iṣe Apo 19

Iṣe Apo 19:11-14