Iṣe Apo 18:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Sila on Timotiu si ti Makedonia wá, ọrọ na ká Paulu lara, o nfi hàn, o sọ fun awọn Ju pe, Jesu ni Kristi na.

Iṣe Apo 18

Iṣe Apo 18:1-15