Iṣe Apo 18:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si nfẹ kọja lọ si Akaia, awọn arakunrin gba a ni iyanju, nwọn si kọwe si awọn ọmọ-ẹhin ki nwọn ki o gba a: nigbati o si de, o ràn awọn ti o gbagbọ́ nipa ore-ọfẹ lọwọ pupọ.

Iṣe Apo 18

Iṣe Apo 18:24-28