Iṣe Apo 18:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si sọkalẹ wá si Efesu, o si fi wọn silẹ nibẹ̀: ṣugbọn on tikararẹ̀ wọ̀ inu sinagogu lọ, o si ba awọn Ju fi ọrọ we ọrọ.

Iṣe Apo 18

Iṣe Apo 18:13-27