Iṣe Apo 17:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awọn ọkunrin kan fi ara mọ́ ọ, nwọn si gbagbọ́: ninu awọn ẹniti Dionisiu ara Areopagu wà, ati obinrin kan ti a npè ni Damari, ati awọn miran pẹlu wọn.

Iṣe Apo 17

Iṣe Apo 17:27-34