Iṣe Apo 17:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Niwọnbi o ti da ọjọ kan, ninu eyi ti yio ṣe idajọ aiye li ododo, nipasẹ ọkunrin na ti o ti yàn, nigbati o ti fi ohun idaniloju fun gbogbo enia, niti o jí i dide kuro ninu okú.

Iṣe Apo 17

Iṣe Apo 17:29-33