Iṣe Apo 17:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun na ti o da aiye ati ohun gbogbo ti mbẹ ninu rẹ̀, on na ti iṣe Oluwa ọrun on aiye, kì igbé ile ti a fi ọwọ́ kọ́;

Iṣe Apo 17

Iṣe Apo 17:20-29