Iṣe Apo 17:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati awọn Ju ti Tessalonika mọ̀ pe, Paulu nwasu ọ̀rọ Ọlọrun ni Berea, nwọn si wá sibẹ̀ pẹlu, nwọn rú awọn enia soke.

Iṣe Apo 17

Iṣe Apo 17:11-16