Iṣe Apo 17:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lọgan awọn arakunrin si rán Paulu on Sila lọ si Berea li oru: nigbati nwọn si de ibẹ̀, nwọn wọ̀ inu sinagogu awọn Ju lọ.

Iṣe Apo 17

Iṣe Apo 17:4-15