Iṣe Apo 16:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iran kan si hàn si Paulu li oru: ọkunrin kan ara Makedonia duro, o si mbẹ̀ ẹ, wipe, Rekọja wá si Makedonia, ki o si ran wa lọwọ.

Iṣe Apo 16

Iṣe Apo 16:4-15